Category:

Alága gbogbogbo orílédè àná fún ẹgbẹ́ òṣèlú APC,Inuwa Abdulkabir ti papọ̀dà

Alága(iwọ̀ orùn-àríwá),fún gbogbo ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress,Inuwa Abdulkabir ti papọ̀dà. Ó kú ní fẹ̀rẹ̀kùtù ọjọ́ ajé látàrí àìsàn rán pé tí ó ṣe é. Ọ̀rẹ́ rẹ̀ àti ẹni tí ó tún jẹ́ akegbẹ́ rẹ̀ nínú ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní àsìkò ìgbà tí Adams Oshiomole jẹ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú náà,ẹni tí ó jẹ́ igbákejì […]

Continue Reading
Posted On :
Category:

Gómìnà Akeredolu tı gba ìwòsàn

Lẹ́yìn àìmọye ọjọ́ tí gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó ti lùgbàdì ààrùn korónà ni ó ti wà ní ìyàsọ́tọ̀, àyẹ̀wò ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó Arákùnrin Akeredolu, kò ní ààrùn kọ̀rónà mọ́. Gómìnà Akeredolu ni ó sọ́ eléyìí di mímọ̀ nínú ìròyìn ọjọ́ ajé.Ó sọ wípé àwọn dókítà fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé […]

Continue Reading
Posted On :
Category:

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó sí gbogbo ilé ìjọsìn padà

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó, Arákùnrin Oluwarotimi Akeredolu, ti pàṣẹ wípé kí gbogbo ilé ìjọsìn jẹ́ ṣíṣí láti ọ̀la lọ. Àwọn ètò ìjọsìn, gẹ́gẹ́ bí Gómìnà ṣe sọ, gbọ́dọ̀ jẹ́ ṣíṣe pẹ̀lú mímú ìlànà tí ìjọba làkalẹ̀ lò. Arákùnrin Akeredolu wípé gbogbo ṣíṣe ètò ìjọsìn yí ó bẹ̀rẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí àwọn tí jókòó pẹ̀lú gbogbo àwọn […]

Continue Reading
Posted On :
Category:

Ìjọba àpapọ̀ Orílèdè ti fẹ́ sọ àwọn ìlànà tí ó ní se pẹ̀lú ìwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́

Ìjọba àpapọ̀ Orílèdè ti sọ wípé àwọn máa sọ àwọn ìlànà tí ó ní se pẹ̀lú ṣíṣí àwọn ilé ìwé tí wọ́n tìpa káàkiri orílèdè. Alága àwọn agbófinró tí óhún rí sí ààrùn kòrónà, Boss Mustapha, ni ó sọ di mímọ̀ ní ìgbàtí óhún sọ̀rọ̀ ní Abuja ní ọjọ́ ojọ́rú. Ní ìgbà tí óhún kí […]

Continue Reading
Posted On :
Category:

Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APGA ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní ìpínlẹ̀ Abia

Alága ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Grand Alliance, (APGA), ní ìjọba ìbílẹ̀ Ohafia ní ìpínlẹ̀ Abia, Olóyè Kalu Mba Nwoke, ni ó ti fi ẹgbẹ́ náà sílè tí ó sì lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, (APC). Mba Nwoke, tí ó sọ̀rọ̀ ní Ohafia, ní òpin ọ̀sẹ̀, sọ wípé òhun ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ […]

Continue Reading
Posted On :