Ní ọjọ́ ojọ́rú,ni ìjọba ìpínlẹ̀ Borno kéde ikú ẹnì kejì tí kòrónà pa. Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno, Alhaji Umar Kadafur,ẹni tí ó tún jẹ́ alága ìgbìmọ̀ ńlá lórí ààrùn kòrónà ní ìpínlẹ̀ naa ni ó sọ́ di mímọ̀ ní ọjọ́ ojọ́rú ní ìgbàtí óhún jábọ̀ lórí ààrùn kòrónà ní ìpínlẹ̀ […]