Alága àjo tí óhún rí sí àwon omo orílèdè nàjíríà tí óhún gbé òkè òkun(NIDCOM)Abike Dabiri-Erewa ni ó ko ìwé àwon tí ààrùn kòrónà ti se ikú pa ní òkè òkun nínú fídíò tí ó gbé sí orí twitter láti fi se ìdágbére ìkehìn fún won. Dabiri-Erewa kó wípé:”kí olórun […]