Ní agogo mésan kojá ìséjú méwa,ojó àìkú,ojó kejìlá,odún tí awàyí ni àwon àjo tóhún mójútó àjàkálè ààrùn ní orílèdè nàíjíríà (NCDC)ni wón tún ti rí àwon máàrún tí ó ní ààrùn kòrónà ní orílèdè nàíjíríà tí ósì jé kí àpapò àwon tí ó ní jé métàlélógúnléláàdórun. Àwon àjo yìí jé […]

ORÍLÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ TÚN TI RÍ ÀWON TÓ TÚN NÍ ÀÀRÙN LÁÁSÀ FIFÀ,NÍ ÀPAPÒ ÀWON TÓ NÍ JÉ EGBÈRINLÉMÉTALÉLÓGÓTA Àjo tí óhún mójú tó àjàkálè ààrùn ní ilè nàíjíríà(NCDC)ni ó so di mímò ní orí aféré wípé àpapò àwon tí ó ní ààrùn lásá fifà náà ti jé egbèrinlémétalélógóta ní odún […]