Gómìnà Oyetola yí ò bá àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀sun sọ̀rọ̀ ní agogo mẹ́wàá òní. Gómìnà yí ó sọ̀rọ̀ lórí ibi tí ìpínlẹ̀ náà bá dé lórí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ ààrùn kòrónà, yí ó sì kéde ohun titun tí wọ́n ní láti ṣe láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ ààrùn kòrónà ní ìpínlẹ̀ náà. Gbogbo […]