Olórí àwon Òsìsé Ológun,Bùrátài lóti kólo sí apá àríwá ìlà-õrùn ilè nàíjíríà Olórí òsìsé àwon ológun (COAS),LT Gen TY Buratai,ni óti kólo pátapáta sí apà àríwá ìlà-õrùn nàíjíríà ní ibi tí yí oti máa mójútó,àti tí óti má a da rí gbogbo àwon isé gbogbo kákìri ilè nàjíríà. Ódi mímò […]