Kòju àwọn ọgbọ̀n ènìyàn lọ, ni ó ti yarí wípé àwọn kò fẹ́ ilé ìyàsótọ̀ ìjọba ní ìpínlẹ̀ Gombe. Alága, àwọn ìgbìmọ̀ agbófinró tí óhún rí sí ààrùn kòrónà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Idris Mohammed, ní ọjọ́ ajé ni àwọn ènìyàn méjìlá péré ni òhún le sọ̀rọ̀ nípa wọn, wípé àwọn ìgbìmọ̀ yòókù […]

Orílèdè Chile ṣe àkọsílẹ̀ àwọn tí ó ní ààrùn kòrónà ní ọjọ́ ajé, pẹ̀lú bí àwọn ẹgbẹ̀rún ènìyàn tí ó ní ààrùn náà láàárín ọjọ́ kan, eléyìí tí àwọn mínísítà méjì tí ó wà lára ìṣe ìjọba Ààrẹ Sebastián Pinera. Àwọn elétò ìlera ṣe ìkéde àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rinlémárùndínlọ́gọ̀rún(4,895)tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ […]

Àjọ tóhún rísí ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Enugu ni ó ti ṣe àkọsílẹ̀ ènìyàn mẹ́rin tí ó ní ààrùn kòrónà. Nínú ohun tí komísónà fún ètò ìlera, Dókítà Ikechukwu Obi, sọ ní alẹ́ ọjọ́ àbámẹ́ta, ní kété tí àwọn àjọ tí óhún mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílèdè Nàíjíríà(NCDC)ṣe ìkéde tán,ni […]

Òkan lára àwọn asòfin tí óhún sojú àrin gbùngbùn ìpínlẹ̀ Nassarawa ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Nassarawa,Ọ̀gbẹni Sule Adamu, tí kú látàrí ààrùn kòrónà. Gómìnà ìpínlè náà Abdullahi Sule, ni ó sọ di mímọ̀ ní ọjọ́ àìkú ní ìgbàtí óhún bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀. Ó ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ […]

Ìjọba Ìpínlẹ̀ kánò ti kéde àkọsílẹ̀ ikú ènìyàn méjì látàrí ààrùn kòrónà. Mínísítírì fún ètò ìlera ìjọba Ìpínlẹ̀ náà ni ó sọ́ di mímọ̀ ní ọjọ́ ajé, ọjọ́ ketàdínlọ́gbọ̀n,oṣù kẹrin. Ó ní ní dédé bí agogo méjìlá kọjá ìsẹ́jú mẹ́ẹ̀dógún ọ̀sán, ní ọjọ́ ketàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ọdún tí awàyí. “kọ́ni […]