Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti kéde ènìyàn méjì tí ó ní ààrùn kòrónà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun,tí ó mú kí àpapọ̀ àwọn tí ó ní ààrùn kòrónà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun jẹ́ mẹ́wàá. Kọmísọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun,Dókítà Rafiu Isamotu, ní orí ẹ̀rọ ayélujára túítà ní ọjọ́ àìkú ni ó sọ […]