Wọ́n tún ti rí àwọn mẹ́rin tí ó ní ààrùn Ẹ̀bólà ní orílèdè congo. Àwọn àjọ tóhún rísí ètò ìlera ní gbogbo àgbáyé(WHO)ti Ọ́fìsì Afrika ni ó fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ni orí túítà @WHOAFRO ní ọjọ́ ojórú. Ohun tí wọ́n kò síbè ni :Who tún tẹ̀síwájú láti máa fi […]