Ààrẹ Mùhámádù Bùhárí yíì ó bá gbogbo àwọn ọmọ orílèdè Nàíjíríà sọ̀rọ̀ ní agogo mẹ́jọ alẹ́ òní. Elèyìí di mímọ̀ ni orí túítà abenugan Ààrẹ, Mallam Garba Shehu. Eléyìí má a jẹ́ elẹ́kẹta tí Ààrẹ yí ò bá àwọn ọmọ orílèdè Nàíjíríà sọ̀rọ̀ lórí àjàkálẹ̀ ààrùn kòrónà. Ẹwo ohun tí […]