Ààrẹ Mùhámádù Bùhárí yíì bá àwon ọmọ Nàíjíríà sọ̀rọ̀ ní agogo méje alẹ́ òní(ọjọ́ ajé). Onímọ̀ràn pàtàkì sí ààre lórí sí sọ hùn kan di mímọ̀ fún àwọn èèyàn,Fẹmi Adesina, ni ó sọ di mímọ̀ nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀. Bótilẹ̀ jẹ́ wípé kò sọ ní pàtó ohun tí Ààrẹ fẹ́ sọ̀rọ̀ […]