0 0
Read Time:1 Minute, 30 Second

Àṣà Yorùbá jẹ́ àṣà tí ọ́ tọ́, tí ó ṣì gbayì púpọ̀, gẹ́gẹ́ bí àwọn èdè yòókù ṣe ní àwọ̀n ònkà òwe, àti ábídí tí wọ́n, bẹ́ẹ̀ni èdè yorùbá náà ṣe ní ti rẹ̀.

Láti lè mọ púpọ̀ nípa àṣà yorùbá, ilé isẹ́ Affairstv ti se ètò fún yín láti rànyín lọ́wọ́ láti mọ òwe yorùbá dáradára.

(31). Ilé la tí ń kó ẹ̀so rò de.

Charity begins at Home.

(32). Eewu ń bẹ loko Lóngẹ́, Lóngẹ́ fun ara rẹ̀ eewu ni.

There is danger at Longę’s farm

(33). Bí éégún ńlá bá ní òhun ó rí gontò, gontò náà á ní òhun o ri eégún ńlá.

If a big masquerade claims it doesn’t see the smaller masquerade, the small masquerade will also claim it doesn’t see the big masquerade.

(34). Kò sí ęni tí ó ma gùn ęşin tí kò ní ju ìpàkó. Bí kò fę ju ìpàkó, ęşin tí ó ngùn á ję kojū.

No one rides a horse without moving his head, voluntarily or involuntarily.

(35). Bí abá sọ òkò sójà ará ilé eni ní bá

He who throws a stone in the market will hit his relative.

(36). Àgbà kí wà lọjà, kí orí ọmọ titun ó wọ.

Do not go crazy, do not let the new baby look.

(37). Adìẹ funfun kò mọ ara rẹ̀ lágbà

The white chicken does not realize its age.

(38). Ọbẹ̀ kìí gbé inú àgbà mì

The soup does not move round in an elder’s belly.

(39). À ń pe gbẹ́nàgbẹ́nà ẹyẹ àkókó ń yọjú

A sculptor is summoned and the woodpecker shows up.

(40). Gbogbo aláǹgbá da kùn délẹ̀, a ò mọ èyí tí inú ń ro.

All lizards lie flat on their stomach, its difficult to determine which one have stomach ache.

About Post Author

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com
Happy
Happy
0 %
Sad
Sad
0 %
Excited
Excited
0 %
Sleepy
Sleepy
0 %
Angry
Angry
0 %
Surprise
Surprise
0 %

Average Rating

5 Star
0%
4 Star
0%
3 Star
0%
2 Star
0%
1 Star
0%

Leave a Reply