1 0
Read Time:3 Minute, 3 Second

Àṣà Yorùbá jẹ́ àṣà tí ọ́ tọ́, tí ó ṣì gbayì púpọ̀, gẹ́gẹ́ bí àwọn èdè yòókù ṣe ní àwọ̀n ònkà, òwe, àti ábídí tí wọ́n, bẹ́ẹ̀ni èdè yorùbá náà ṣe ní ti rẹ̀.

Láti lè mọ púpọ̀ nípa àṣà yorùbá, ilé isẹ́ Affairstv ti se ètò fún yín láti rànyín lọ́wọ́ láti mọ ònkà yorùbá dáradára.

Yí ò pín ṣí ìṣòrí mẹ́wàá,gbogbo rẹ̀ yó jẹ́ láti ókan títí dé egbẹ̀rún,tí a ó ṣì ma muwá ní ògórùn.

201 = mọ́kànlènígba
202= méjìlènígba
203= mẹ́tàlènígba
204= mẹ́rìnlènígba
205= márùndínláàdọ́fà
206= mẹ́rìndínláàdọ́fà
207= mẹ́tàdínláàdọ́fà
208= méjídínláàdọ́fà
209= mọ́kàndínláàdọ́fà
210= àádọ́fà

211 = okòólénígba dín mẹ́san
212= okòólénígba dín mẹjo
213= okòólénígba dín meje
214= okòólénígba dín mẹ́fa
215= okòólénígba dín marun
216= okòólénígba dín mẹ́rìn
217= okòólénígba dín mẹ́tà
218= okòólénígba dín méjí
219= okòólénígba dín kàn
220= okòólénígba

221 = okòólénígba le kan
222 = okòólénígba àti méjí
223 = okòólénígba àti mẹ́tà
224 = okòólénígba àti mẹ́rìn
225 = okòólénígba àti marùn ún
226 = okòólénígba àti mẹ́fà
227 = okòólénígba àti meje
228 = okòólénígba àti mẹjọ
229 = okòólénígba àti mẹsan
230 = okòólénígba àti mẹwàá

231 = òjìlénígba dín mẹ́sàn án
232 = òjìlénígba dín mẹ́jọ
233 = òjìlénígba dín meje
234 = òjìlénígba dín mẹfa
235 = òjìlènígba dín marun
236 = òjìlènígba dín mẹrin
237 = òjìlènígba dín mẹta
238 = òjìlènígba dín meji
239 = òjìlènígba dín ọkan
240 = òjìlénígba / òjìlérúgba

241 = òjìlénígba lé kan
242 = òjìlénígba lé meji
243 = òjìlénígba lé meta
244 = òjìlénígba lé merin
245 = òjìlénígba lé marun
246 = òjìlénígba lé mefa
247 = òjìlénígba lé meje
248 = òjìlénígba lé mejo
249 = òjìlénígba lé mesan
250 = òjìlénígba lé mewaa

251 = ọ̀tàlénígba din mesan
252 = ọ̀tàlénígba din mejo
253 = ọ̀tàlénígba din meje
254 = ọ̀tàlénígba din mefa
255 = ọ̀tàlénígba din marun
256 = ọ̀tàlénígba din merin
257 = ọ̀tàlénígba din meta
258 = ọ̀tàlénígba din meji
259 = ọ̀tàlénígba din kan
260 = ọ̀tàlénígba/ ọ̀tàlérúgba

261 = ọ̀tàlénígba lé kan
262 = ọ̀tàlénígba lé meji
263 = ọ̀tàlénígba lé mẹta
264 = ọ̀tàlénígba lé mẹrin
265 = ọ̀tàlénígba le marun un
266 = ọ̀tàlénígba le mẹfa
267 = ọ̀tàlénígba le meje
268 = ọ̀tàlénígba le mẹjo
269 = ọ̀tàlénígba le mẹsan an
270 = ọ̀tàlénígba le mẹwaa

271 = ọ̀rìnlénígba din mẹsan
272 = ọ̀rìnlénígba din mẹjo
273 = ọ̀rìnlénígba din meje
274 = ọ̀rìnlénígba din mẹfa
275 = ọ̀rìnlénígba din marun
276 = ọ̀rìnlénígba din mẹrin
277 = ọ̀rìnlénígba din mẹta
278 = ọ̀rìnlénígba din meji
279 = ọ̀rìnlénígba din kan
280 = ọ̀rìnlénígba

281 = ọ̀rìnlénígba lé kan
282 = ọ̀rìnlénígba lé meji
283 = ọ̀rìnlénígba lé meta
284 = ọ̀rìnlénígba lé merin
285 = ọ̀rìnlénígba lé marun un
286 = ọ̀rìnlénígba lé mefa
287 = ọ̀rìnlénígba lé meje
288 = ọ̀rìnlénígba lé mejo
289 = ọ̀rìnlénígba lé mesan
290 = ọ̀rìnlénígba lé mewaa

291 = ọ́ọ̀dúnrún dín mesan
292 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹjo
293 = ọ́ọ̀dúnrún dín meje
294 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹfa
295 = ọ́ọ̀dúnrún dín marun un
296 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹrin
297 = ọ́ọ̀dúnrún dín mẹta
298 = ọ́ọ̀dúnrún dín meji
299 = ọ́ọ̀dúnrún dín kan
300 = ọ́ọ̀dúnrún

About Post Author

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com
Happy
Happy
0 %
Sad
Sad
0 %
Excited
Excited
100 %
Sleepy
Sleepy
0 %
Angry
Angry
0 %
Surprise
Surprise
0 %

Average Rating

5 Star
0%
4 Star
0%
3 Star
0%
2 Star
0%
1 Star
0%

Leave a Reply