
Read Time:28 Second
Àwọn àjọ elétò ìdánwò ìpele ìparí ilé ìwé sẹ́koondírì (WAEC), ni ó ti sọ pé èsì ìdánwò àwọn tí ó kọ WAEC yìí jáde lọla ọjọ́ ajé, ọjọ́ kejì oṣù kọkànlá ọdún tí awàyí.
Àjọ WAEC sọ eléyìí di mímọ ní orí ẹ̀rọ ayélujára túítà wọn, ní ọjọ́ àìkú.
Wọ́n kó wípé : “eléyìí ni láti fi tó gbogbo àwọn tí ó kọ ìdánwò WAEC ní ọdún 2020, wípé èsì ìdánwò náà yí jáde láti ọwọ́ @waecnigeria ní ọla, ọjọ́ ajé, ọjọ́ kejì, ọdún 2020, ní dédé agogo mẹ́wàá àbọ̀ “.
About Post Author
Adegbenro Islamiyat
Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert.
Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com