Gómìnà Akeredolu tı gba ìwòsàn

Lẹ́yìn àìmọye ọjọ́ tí gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó ti lùgbàdì ààrùn korónà ni ó ti wà ní ìyàsọ́tọ̀, àyẹ̀wò ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó Arákùnrin Akeredolu, kò ní ààrùn kọ̀rónà mọ́.

Gómìnà Akeredolu ni ó sọ́ eléyìí di mímọ̀ nínú ìròyìn ọjọ́ ajé.Ó sọ wípé àwọn dókítà fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òhun kò ní ààrùn náà mọ́ lẹ́yìn ìgbà tí àyẹ̀wò fi ìdi rẹ̀ múlẹ̀ ní ẹ̀mejì.

Ìròyìn lẹ́kùnrẹ́rẹ́ tóbáyá.

Ìwé ìròyìn Punch.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

Mon Jul 6 , 2020
Arákùnrin Akeredolu yan Oluwatuyi gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó titun Látàrí ìwé ìfi iṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó tí Ifedayo Abegunde kọ,Gómìnà Rotimi Akeredolu ní ọjọ́ ajé ni ó ṣe ìkéde yíyan Temitayo Oluwatuyi gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé ìjọba Ìpínlẹ̀ titun ní Ìpínlẹ̀ náà. Gómìnà sọ di […]
%d bloggers like this: