Ìjọba àpapọ̀ Orílèdè ti fẹ́ sọ àwọn ìlànà tí ó ní se pẹ̀lú ìwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́

Ìjọba àpapọ̀ Orílèdè ti sọ wípé àwọn máa sọ àwọn ìlànà tí ó ní se pẹ̀lú ṣíṣí àwọn ilé ìwé tí wọ́n tìpa káàkiri orílèdè.

Alága àwọn agbófinró tí óhún rí sí ààrùn kòrónà, Boss Mustapha, ni ó sọ di mímọ̀ ní ìgbàtí óhún sọ̀rọ̀ ní Abuja ní ọjọ́ ojọ́rú.

Ní ìgbà tí óhún kí àwọn ọmọ kú oríre ayẹyẹ àjọyọ̀ ọdún àwọn ọmọ kékeré ó sì tún fi dá wọn lójú, àwọn òbí àti gbogbo àwọn elétò wípé ètò nlọ lórí ṣíṣí ilé ìwé ní àsìkò tó yẹ àti ìgbà tí àbò bá dájú.

“A fi àsìkò yìí rọ àwọn ìjọba ìbílẹ̀,àwọn ọ̀gá ilé ẹ̀kọ́, àti gbogbo àwọn elétò tí ó kù láti máa ṣe àmúlò gbogbo ohun tí yí ó mú ṣíṣí ilé ẹ̀kọ́ ní àsìkò yá.

Ìwé ìròyìn Punch.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

Lagos: We’ll deploy buses to replace okada, tricycles in July

Thu May 28 , 2020
The Lagos state government says buses with certain specifications will be deployed to replace okada, tricycles in some areas in the state. On February 1, the state government enforced the restriction on commercial tricycles and motorcycles in 15 local councils. Despite criticism against the government’s action, Babajide Sanwo-Olu, governor of the state, said the […]
%d bloggers like this: