Asòfin kan kú ní ìpínlẹ̀ Nassarawa látàrí ààrùn kòrónà

Òkan lára àwọn asòfin tí óhún sojú àrin gbùngbùn ìpínlẹ̀ Nassarawa ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Nassarawa,Ọ̀gbẹni Sule Adamu, tí kú látàrí ààrùn kòrónà.

Gómìnà ìpínlè náà Abdullahi Sule, ni ó sọ di mímọ̀ ní ọjọ́ àìkú ní ìgbàtí óhún bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀.

Ó ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ náà yí ó jẹ́ títìpa, tí gbogbo àwọn asofin yí ó sì wà ní ìsémọ́lé láti lè dẹ́kun ìtànkálẹ̀ ààrùn náà ní ìpínlẹ̀ náà.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ tóbáyá. ..

Ìwé ìròyìn Nation.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

ọ̀kan lára àwọn Ọba pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ ní ilé ìyàsótọ̀ ní ìpínlẹ̀ Zamfara

Sun May 3 , 2020
Ọba ìlú Kaura-Namoda ní ìpínlẹ̀ Zamfara, Alhaji Mohammed Asha ti pàdánù ẹ̀mí rẹ̀. Wọ́n sọ wípé ó kú látàrí ààrùn kòrónà. Akọ̀wé gbogbogbò ìpínlẹ̀ Zamfara fún àjọ tí óhún rí sí ìdẹkùn ààrùn,Alhaji Mustafa Jafaru Kaura, wípé olóògbé ti wà ní ilé ìwòsàn ìyàsótọ̀ ní Yariman Bakura, Gusau fún ọjọ́ […]
%d bloggers like this: