Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno àná,Mohammed Goni ti papodà

Gómìnà Alágbáda ìpínlẹ̀ Borno àná,Mohammed Goni ti pàdánù ẹ̀mí rẹ̀.

Gẹ́gẹ́ bí àwọn ìwádi kan ṣe fi hàn,Gómìnà Goni kú sí ilé ìwòsàn aládani kan,ní alẹ́ ọjọ́rú ní ìlú Maiduguri látàrí àìsàn ránpẹ̀.

Ó ṣe Gómìnà ìjọba náà láàrin ọdún 1979 sí 1983.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Borno kò tí sọ̀rọ̀ kankan nípa ikú rẹ̀,ṣùgbọ́n ìròyìn ikú Gómìnà yìí ti gba orí ẹ̀rọ ayélujára kan.

Ìròyìn lẹ́kùnrẹ́rẹ́ láìpẹ́.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

Ìjọba àpapọ̀ Orílèdè ti kéde ọjọ́ etì,ọjọ́ kíní oṣù karùn-ún fún ọludé gbogbogboo

Thu Apr 30 , 2020
Ìjọba àpapọ̀ Orílèdè ti kéde ọjọ́ kíní oṣù karùn-ún,fún ọludé gbogbogboo,láti ṣe ayẹyẹ ọdún àwọn òṣìṣẹ́ káàkiri orílèdè Nàíjíríà. Mísítà fún ètò abẹ́lé,Rauf Aregbesola,tí ó kéde oludé yìí nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀,ni ó kí àwọn òṣìṣẹ́ orílèdè Nàíjíríà kú sùúrù,ìtẹ̀mọra,àti àgbọ́yé wọn pàápàá jùlọ,ìfọwọ́sowọ́pọ̀ wọn pẹ̀lú akitiyan ìsèjọba Ààrẹ Buhari láti […]
%d bloggers like this: