Warning: sprintf(): Too few arguments in /home/affairst/public_html/wp-content/themes/default-mag/assets/libraries/breadcrumb-trail/inc/breadcrumbs.php on line 254

Ìjọba Ìpínlẹ̀ kánò ṣe àkọsílẹ̀ ikú ènìyàn méjì látàrí ààrùn kòrónà

Ìjọba Ìpínlẹ̀ kánò ti kéde àkọsílẹ̀ ikú ènìyàn méjì látàrí ààrùn kòrónà.

Mínísítírì fún ètò ìlera ìjọba Ìpínlẹ̀ náà ni ó sọ́ di mímọ̀ ní ọjọ́ ajé, ọjọ́ ketàdínlọ́gbọ̀n,oṣù kẹrin.

Ó ní ní dédé bí agogo méjìlá kọjá ìsẹ́jú mẹ́ẹ̀dógún ọ̀sán, ní ọjọ́ ketàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ọdún tí awàyí.

“kọ́ni lé gbé ilé,fún àbọ̀ èmi”

“Àpapọ̀ àwọn tí ó ní ààrùn kòrónà ní ìpínlẹ̀ Kánò jẹ́ mẹ́tàdínlógọ́rin, kò sí ẹni tí ó ti rí ìwòsàn, ènìyàn mẹ́ta ti kú”

Ìwé ìròyìn Daily Post

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

BREAKING: President Buhari to address Nigerians today (See Time)

Mon Apr 27 , 2020
President Muhammadu Buhari will today address Nigerians by 8pm. This was made known in a tweet by the official Spokeperson of the President, Mallam Garba Shehu. This will be the third time President Buhari will address Nigerians on COVID-19 update. See Tweet Television, radio and other electronic media stations are […]
%d bloggers like this: