Ààrẹ orílèdè Nàíjíríà;Bùhárí yíì ó bá àwon ọmọ Nàíjíríà sọ̀rọ̀(Ẹwo Àkókò)

Ààrẹ Mùhámádù Bùhárí yíì ó bá gbogbo àwọn ọmọ orílèdè Nàíjíríà sọ̀rọ̀ ní agogo mẹ́jọ alẹ́ òní.

Elèyìí di mímọ̀ ni orí túítà abenugan Ààrẹ, Mallam Garba Shehu.

Eléyìí má a jẹ́ elẹ́kẹta tí Ààrẹ yí ò bá àwọn ọmọ orílèdè Nàíjíríà sọ̀rọ̀ lórí àjàkálẹ̀ ààrùn kòrónà.

Ẹwo ohun tí ó kọ sí túítà

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

Àwọn ajínigbé tí ó gbé komísónà ní ìpínlẹ̀ Ekiti bẹ̀rẹ̀ fún ọgbọ̀n Míllíònù

Mon Apr 27 , 2020
Àwọn ajínigbé tí ó gbé komísónà fún ètò ǹkan oko ìpínlẹ̀ Ekiti, Ọ̀gbeni Folorunso Olabode,ní ọjọ́ ajé,ni ó sọ fún àwọn ẹbí rẹ̀ wípé wọ́n hún bèrè ọgbọ̀n Míllíònù kí wọ́n tó le fi òhun sílẹ̀. Kò sí ẹni tí ó mọ àwọn ajínigbé tí ó gbé komísónà yìí ní […]
%d bloggers like this: