Díẹ̀ nínú àwọn òwe Yorùbá

Àṣà Yorùbá jẹ́ àṣà tí ọ́ tọ́, tí ó ṣì gbayì púpọ̀, gẹ́gẹ́ bí àwọn èdè yòókù ṣe ní àwọ̀n ònkà òwe, àti ábídí tí wọ́n, bẹ́ẹ̀ni èdè yorùbá náà ṣe ní ti rẹ̀.

Láti lè mọ púpọ̀ nípa àṣà yorùbá, ilé isẹ́ Affairstv ti se ètò fún yín láti rànyín lọ́wọ́ láti mọ òwe yorùbá dáradára.

1)kò sí ohun tóle, tí kìrọ́ọ̀.
There is nothing that is hard,that cannot become soft.

2).ìwákúùwá là ń wá ǹkan tó bá sọnù.
Lost items are searched for anyhow.

3)Ọlọ́run tó ńṣe ọbẹ̀,kò kúrò ní ìdí àrò.
God who is cooking the soup, has not left the kitchen.

4)ọ̀rọ̀ gbogbo kì ì ṣé lórí alábahun.
Every issue cannot but involve the tortoise.

5)À ń kíyèsí gẹ̀gẹ̀ kó má gba ọrùn ká.
One ought to promptly attempt to goiter,less it overwhelms the neck.

6)A kì gbé inú ilé ẹni ká fi ọrùn rọ́.
One cannot stay in one’s home&strain one’s neck.

7)Atẹ́gùn tó wọ ilé ká sọ ní yàrá,ẹni tó wọ ti ẹ̀ kó má s’àfira.
The wind that blew into the house,and cleared the. Clothes in the rooms cautioned those who wore theirs not to be tardy.

8)Bí kùkùté ṣe kéré tó,kò sí ẹni tó le fi ẹsẹ̀ fà á tu.
As small as the free stumps,No one can uproot it with foot.

9)Tí ọ̀rọ̀ bá pẹ́ á dìtàn.
When an issue tarries,it will eventually become history.

10)A kì í fi iná sí orí òrùlé sùn.
No one goes to sleep with the roof of his house on fire.

11)A kì fi ẹ̀tẹ́ sílẹ̀ pa làpálàpá.
We ought not to leave leprosy unattended & focus on treating ringworm.

12)kò sí ohun tó ní ìbẹ̀rẹ̀,tí kò ní òpin.
There is nothing that has a beginning,that won’t have ending.

13)oore kéré, oore tóbi, oore lore yóò ma jẹ́.
Whether small or big,a kind act remains a kind act.

14)Bí ẹ̀mí bá wà, ìrètí ń bẹ.
As long as there is life,there is hope.

15)Èdí kí í mú ọjọ́ kó málà.
No charm can act upon the day&keep it drown.

16)Òkun kì í hó ruru,kí á wa ruru.
Never paddle windly in a stormy sea.

17)A kì mọ orúkọ Ọlọ́run, kíí ìyà jẹni.
One don’t know God’s name and still suffer.

18)Ẹni sọ̀rọ̀ púpọ̀ yó sìsọ,àsọju lóhún mú ìya ọba,pe ararẹ̀ ní ìyá ọ̀bọ.

19)Díẹ̀ díẹ̀ ni imú Ẹlẹ́dẹ̀ ń wọgbà.

Attend to a small problem before it becomes uncontrollable.

20)Tí òjò bá kọ̀ tí kò rọ̀,ìyẹn kò ní ká sọ pè kí òkun ya wọ̀lú.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

Guru Maharaji sends message to Buhari on Coronavirus

Sun Apr 26 , 2020
Spiritual leader, Satguru Maharaji, has called on President Muhammadu Buhari to release more money as Nigerians observe the nationwide lockdown to curb the spread of Coronavirus. The prophet made the call on Sunday while addressing newsmen at his Maharaji Village, NAN reports. The sect leader appealed to Buhari to provide […]
%d bloggers like this: