Àwọn agbófinró kánò mú àwọn lèmọ́mù mẹ́ẹ̀dógún látàrí rírú òfin Kóní Ilé gbé ílé

Àwọn olọ́pàá ìpínlẹ̀ kánò sọ wípé ó ju àwọn agbágbọ̀lù ọgbọ̀n lọ tí àwọn ti mú látàrí rírú òfin kónígbélé.

Òṣìṣẹ́ ìbátan ti àwọn olọ́pàá ní ìpínlẹ̀ kánò,Abdulahi Haruna ni ó sọ́ di mímọ̀ fún àwọn ìwé ìròyìn Nation ní orí ẹ̀rọ ìbánisòrọ̀,ó ní ibi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n ti mú wọn.

Haruna ṣe àfikún wípé wọ́n tún ti mú àwọn lèmọ́mù mẹ́ẹ̀dógún míràn látàrí rírú òfin Kóní Ilé gbé ílé.

Àwọn olọ́pàá tún sọ wípé èyíkéyìí nínú àwọn olórí ẹṣin wọ̀nyí(Mùsùlùmí tàbí Kristẹni)tí ó bá rú òfin yìí máa di mímú.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

Wọ́n pa àwọn Olọ́pàá méjì ní ilé isẹ́ Àtíkù

Wed Apr 22 , 2020
Àwọn olọ́pàá méjì ti pàdánù èmi wọn ní ìpínlẹ̀ Adamawa. Àwọn olọ́pàá yìí ni DSP Gbenga,Asp Yohanna,ni wọn pa ní RicoGado,ilé isẹ́ Igbákejì ààre àná Atku Abubakar,tí wọ́n tí hún ṣe oúnjẹ àwọn ẹranko. Wọ́n ní àwọn apànìyàn ni ó pa wọ́n ní ìgbàtí wọ́n lọ ṣe àbẹ̀wo ibi tí […]
%d bloggers like this: