Ààrẹ Bùhárí pàdánù ọkàn lára àwọn olùsọ-ara eni rẹ̀

Òkan lára àwọn olùsọ ara-ẹni Ààrẹ Mùhámádù Bùhárí,Lawal Mato,ni ó papòdà ní ọjọ́ ìsẹgun.

Ó tó bí ọdún mẹ́ta tí àìsàn ìtọ̀ súúgà hún bá fínra,abenugan Ààrẹ,Garba Shehu, ní ó kéde ọ̀rọ̀ náà.

Ààrẹ ṣe àpèjúwe olùsọ yìí,ẹni tí ó ti hún bá ṣíṣe kó tó di wípé ó di ààre ní ọdún 2015,”ó ní wípé ó jé òṣìṣẹ́ takuntakun, tí ó ṣì mọ isẹ rẹ̀ bí isẹ́”.

Ààrẹ gbà ní àdúrà wípé Ọlọhun máa fi ọ̀run kẹ,Ọlọhun á dẹ̀ mú àwọn ẹbí rẹ̀, àti ìjọba Ìpínlẹ̀ Jigawa ní ọkàn le.

Olùsọ Mato jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùsọ Ààrẹ aana, Umar Musa Yar’Adua, tí Ààrẹ Bùhárí sì tún gbà fún olùsọ ara-ẹni rẹ̀.

Adegbenro Islamiyat

Adegbenro Islamiyat is a Yoruba Language Communication expert. She has a wide experience in writing news, stories and articles in Yoruba language. She also doubles as a Programme presenter and voice over expert. Message her on adegbenroislamiyat74@gmail.com

Leave a Reply

Next Post

BREAKING: Abia closes private hospital treating COVID-19 patients

Tue Apr 21 , 2020
Abia Governor Okezie Ikpeazu has announced the indefinite closure of a private hospital where the two index cases of the coronavirus in the state were receiving medical attention before their referral to the Federal Medical Centre (FMC) Umuahia. Ikpeazu, in a media briefing in Umuahia, the state capital, added that […]
%d bloggers like this: